價格:免費
更新日期:2017-11-25
檔案大小:3.7M
目前版本:2.0
版本需求:Android 2.3 以上版本
官方網站:http://twogbs.com/
Email:wogbs@live.co.uk
聯絡地址:35 Lower Road Erith United Kingdom DA8 1AY
The Yoruba translation of book called Jesus Didactic Encounters is the first book after the Bíbélì Mímó̩ Onítumò̩ (BMO) with all the words with the correct accent.
These book, called My Didactic Encounters With Jesus; Christian: Jesus Didactic Encounters came by virtue of what Our Lord Jesus did for me and through me.
The book did not only reveal that Jesus is still working miracles through His beloved followers, but also a revelation and testament that they can be made to work and shine in the way of the Lord Jesus Christ.
Ìwé Ìjíròrò Ìbápàdé Jésù kò dúro lórí i fífihàn pé Jésù Ksístì tún ń s̩e is̩é̩ ìyanu lódè òní nìkan, s̩ùgbó̩ ó ń fi e̩sè̩ e̩ni lé ò̩nà bí ìwo̩ papàá ti s̩e lè di e̩ni tí O̩ló̩run ńlò láti má a s̩e is̩é ìyanu pè̩lú ìfo̩wó̩-sowó̩-pò̩ pè̩lú u Jésù.
Àwo̩n àfikún tí a fi sí è̩hìn ìwé yìí jé̩ ìdánilé̩kó̩ fún à ti kó̩-ni ní mímo̩ kíka èdè Yorúbà. Ìwé náà kò fi ète rè̩ mo̩ lórí èyìí, s̩ùgbó̩n ó kún fún ò̩kan-kòjò̩kan òwé àti e̩wà e̩nu Yorùbá tí kò láfiwé. A kì í jiyàn o̩se̩ hó o̩se̩ kò hó lódò lo̩rò̩ rè̩.
Pàtàkì jùlo̩, ìwé náà kún fún ìtó̩-ni tí a ti dán wò láti mo̩ E̩lé̩dá re̩ dájú sáká àti irúfé̩ bí a ti í rín ní ò̩ná yóó gba-ni ló̩wó̩ ìke̩kùn àwo̩n agbára òkùkù; àti rírí ò̩nà àlùyo̩ ló̩wó̩ àwo̩n agbára búburú àti sátáni tí í s̩e èsù.
Ìwé yìí mú un ló̩kúnkúndùn pé tí ó bá s̩e pé ayé yìí níkan ni a ní ìrètí mo̩; a jé̩ ò̩kan nínú àwo̩n abòsì jùlo̩. Ó fi ò̩nà à tí rí Jésù kí o tó rí ikú hàn gbànn̄gba.
Lo ó bí i ìwé tí ó jé̩ wí pé e̩nìkans̩os̩o ni ó lè lò ó lé̩è̩kan.
A kò fi àse̩ fún e̩niké̩ni láti s̩e àtúntè̩, tabí láti s̩e àdàko̩, tàbí láti tún ìwé yìí kà sí inú kò̩pútà, tàbí kí á ká a sí inú kásé̩è̩tì (cassette), è̩ro̩ ìbánisò̩rò̩ alágbéká, è̩ro̩ orin alágbéká, tàbí CD/DVD, tàbí irúfé̩ e̩ro̩ tí a lè fi n̄ǹkan tàbí ò̩rò̩ pamó̩ sí; tàbí fún gbígbó̩ lòdì sí èrògbà ti irúfé̩ mìíran tí a so̩, tàbí tí a kò so̩ nígbà pínpín ìwé náà nigbà tí a pín in. E̩ni tí ó bá s̩e lòdì sí èyí fi hàn gban̄gba wí pé kò fé̩ ìtànká ìhìn rere.
Owó tí a bá rí nínú pín-pín ìwé yìí ni a ń lò fún títèsíwájú ìpín-fún-ni ò̩rò̩ O̩ló̩run. Fi e̩nu kò pè̩lú ìlérí fún Jésù Krístì Olúwa wí pé o gba ètò ìwé yìí ló̩nà è̩tó̩, àti wí pé o kò ní fi fún e̩niké̩ni ló̩nà àìtó̩.
A ń retí bí O̩ló̩run bá ti fi sí yín ní okàn: ò̩rò̩ ìgba-ni-ní-yànjú, ìrànló̩wó̩, è̩bùn, owó fún ètò títe̩ Bíbélì tàbí ohun èlò fún àseyorí àti ìtè̩síwájú isé̩ Bíbélì Onítumò̩ láti ò̩dò̩ yín.
A fi ore-ò̩fé̩ fún e̩niké̩ni tí ó bá mo̩ dúdùn o̩bè̩ inú ìwé yìí láti yí i sí èdè wo̩n pè̩lú ìs̩àkóso e̩gbé̩ Bíbélì (The Word Of God Bible Society).
Tó̩ o̩ wò kí o mò̩ pé rere l’Olúwa!